Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò àwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́.

Isaiah 2:16 in English

Isaiah 2:16 · Berean Standard Bible

against every ship of Tarshish,* and against every stately vessel.

Context

14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá àti àwọn òkè kéékèèké, 15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga àti àwọn odi ìdáàbòbò, 16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò àwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́. 17Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba a ó sì rẹ ìgbéraga ènìyàn sílẹ̀, Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà, 18gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.