Isaiah 2:14
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá àti àwọn òkè kéékèèké,
Isaiah 2:14 in English
Isaiah 2:14 · Berean Standard Bible
against all the tall mountains, against all the high hills,
Context
12Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́
fún gbogbo agbéraga àti ọlọ́kàn gíga
nítorí gbogbo àwọn tí a gbéga (ni a ó rẹ̀ sílẹ̀), 13nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó
àti gbogbo óákù Baṣani, 14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá
àti àwọn òkè kéékèèké, 15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga
àti àwọn odi ìdáàbòbò, 16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò
àwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.