Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó àti gbogbo óákù Baṣani,

Isaiah 2:13 in English

Isaiah 2:13 · Berean Standard Bible

against all the cedars of Lebanon, lofty and lifted up, against all the oaks of Bashan,

Context

11Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀ a ó sì tẹrí ìgbéraga ènìyàn ba, Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà. 12Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́ fún gbogbo agbéraga àti ọlọ́kàn gíga nítorí gbogbo àwọn tí a gbéga (ni a ó rẹ̀ sílẹ̀), 13nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó àti gbogbo óákù Baṣani, 14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá àti àwọn òkè kéékèèké, 15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga àti àwọn odi ìdáàbòbò,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.