Hosea 13:7
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún, Èmi yóò fi ara pamọ́ dè wọ́n lọ́nà bí i ẹkùn.
Hosea 13:7 in English
Hosea 13:7 · Berean Standard Bible
So like a lion I will pounce on them; like a leopard I will lurk by the path.
Context
5Mo ṣe ìtọ́jú rẹ ní aginjù,
ní ilẹ̀ tí ó gbẹ tí kò ní omi. 6Wọn ni ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí mo fún wọn ní oúnjẹ,
Nígbà tí wọ́n ní ìtẹ́lọ́rùn tan wọ́n di agbéraga.
Nígbà náà ni wọ́n sì gbàgbé mi. 7Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún,
Èmi yóò fi ara pamọ́ dè wọ́n lọ́nà bí i ẹkùn. 8Beari igbó tí a já ọmọ rẹ̀ gbà,
Èmi yóò bá wọn jà bí?
Èmi yóò sì fà wọ́n ya
bí ìgbà tí ẹkùn bá fa ara wọn ya
bi ẹranko búburú ni èmi yóò fa wọn ya. 9“A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli,
nítorí pé ìwọ lòdì sí mi, ìwọ lòdì sí olùrànlọ́wọ́ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.