Hosea 13:9
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli, nítorí pé ìwọ lòdì sí mi, ìwọ lòdì sí olùrànlọ́wọ́ rẹ.
Hosea 13:9 in English
Hosea 13:9 · Berean Standard Bible
You are destroyed, O Israel, because you are against Me— against your helper.
Context
7Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún,
Èmi yóò fi ara pamọ́ dè wọ́n lọ́nà bí i ẹkùn. 8Beari igbó tí a já ọmọ rẹ̀ gbà,
Èmi yóò bá wọn jà bí?
Èmi yóò sì fà wọ́n ya
bí ìgbà tí ẹkùn bá fa ara wọn ya
bi ẹranko búburú ni èmi yóò fa wọn ya. 9“A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli,
nítorí pé ìwọ lòdì sí mi, ìwọ lòdì sí olùrànlọ́wọ́ rẹ. 10Níbo ni ọba rẹ gbé wà nísinsin yìí kí ó bá à le gbà ọ là?
Níbo ni àwọn olórí ìlú yín wà,
àwọn tí ẹ sọ pé,
‘Fún wa ní ọba àti ọmọ-aládé’? 11Nítorí èyí nínú ìbínú mi ni mo fún un yín ní ọba,
nínú ìbínú gbígbóná mi, mo sì mú un kúrò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.