Native Bible

Genesis 10:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani.

Genesis 10:6 in English

Genesis 10:6 · Berean Standard Bible

The sons of Ham: Cush, Mizraim, Put, and Canaan.

Context

4Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. 5(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). 6Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani. 7Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama ni: Ṣeba àti Dedani. 8Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.