Native Bible

Genesis 10:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.

Genesis 10:4 in English

Genesis 10:4 · Berean Standard Bible

And the sons of Javan: Elishah, Tarshish, the Kittites, and the Rodanites.*

Context

2Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi. 3Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma. 4Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. 5(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). 6Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.