Native Bible

Genesis 10:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi.

Genesis 10:2 in English

Genesis 10:2 · Berean Standard Bible

The sons of Japheth: Gomer, Magog, Madai, Javan, Tubal, Meshech, and Tiras.

Context

1Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi. 2Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi. 3Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma. 4Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.