Native Bible

Genesis 10:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.

Genesis 10:3 in English

Genesis 10:3 · Berean Standard Bible

The sons of Gomer: Ashkenaz, Riphath, and Togarmah.

Context

1Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi. 2Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi. 3Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma. 4Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. 5(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.