Gẹnẹsisi 10:5
Genesis 10:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀).
Genesis 10:5 in English
Genesis 10:5 · Berean Standard Bible
From these, the maritime peoples separated into their territories, according to their languages, by clans within their nations.
Context
3Àwọn ọmọ Gomeri ni:
Aṣkenasi, Rifati àti Togarma. 4Àwọn ọmọ Jafani ni:
Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. 5(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). 6Àwọn ọmọ Hamu ni:
Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani. 7Àwọn ọmọ Kuṣi ni:
Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.
Àwọn ọmọ Raama ni:
Ṣeba àti Dedani.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.