Gẹnẹsisi 10:7
Genesis 10:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama ni: Ṣeba àti Dedani.
Genesis 10:7 in English
Genesis 10:7 · Berean Standard Bible
The sons of Cush: Seba, Havilah, Sabtah,* Raamah, and Sabteca. And the sons of Raamah: Sheba and Dedan.
Context
5(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). 6Àwọn ọmọ Hamu ni:
Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani. 7Àwọn ọmọ Kuṣi ni:
Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.
Àwọn ọmọ Raama ni:
Ṣeba àti Dedani. 8Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. 9Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.