Gẹnẹsisi 10:8
Genesis 10:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
Genesis 10:8 in English
Genesis 10:8 · Berean Standard Bible
Cush was the father of Nimrod, who began to be a mighty one * on the earth.
Context
6Àwọn ọmọ Hamu ni:
Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani. 7Àwọn ọmọ Kuṣi ni:
Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.
Àwọn ọmọ Raama ni:
Ṣeba àti Dedani. 8Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. 9Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.” 10Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni Babeli, Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.