Native Bible

Genesis 10:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi.

Genesis 10:1 in English

Genesis 10:1 · Berean Standard Bible

This is the account of Noah’s sons Shem, Ham, and Japheth, who also had sons after the flood.

Context

1Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi. 2Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi. 3Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.