1 Kronika 6:17
1 Chronicles 6:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.
1 Chronicles 6:17 in English
1 Chronicles 6:17 · Berean Standard Bible
These are the names of the sons of Gershom: Libni and Shimei.
Context
15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari. 16Àwọn ọmọ Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari. 17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 19Àwọn ọmọ Merari:
Mahili àti Muṣi.
Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Lefi tí a kọ ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.