1 Kronika 6:18
1 Chronicles 6:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Kohati: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
1 Chronicles 6:18 in English
1 Chronicles 6:18 · Berean Standard Bible
The sons of Kohath: Amram, Izhar, Hebron, and Uzziel.
Context
16Àwọn ọmọ Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari. 17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 19Àwọn ọmọ Merari:
Mahili àti Muṣi.
Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Lefi tí a kọ ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn. 20Ti Gerṣoni:
Libni ọmọkùnrin rẹ̀, Jahati.
Ọmọkùnrin rẹ̀, Simma ọmọkùnrin rẹ̀,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.