1 Kronika 6:19
1 Chronicles 6:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Lefi tí a kọ ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn.
1 Chronicles 6:19 in English
1 Chronicles 6:19 · Berean Standard Bible
The sons of Merari: Mahli and Mushi. These are the clans of the Levites listed according to their fathers:
Context
17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 19Àwọn ọmọ Merari:
Mahili àti Muṣi.
Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Lefi tí a kọ ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn. 20Ti Gerṣoni:
Libni ọmọkùnrin rẹ̀, Jahati.
Ọmọkùnrin rẹ̀, Simma ọmọkùnrin rẹ̀, 21Joah ọmọkùnrin rẹ̀,
Iddo ọmọkùnrin rẹ̀, Sera ọmọkùnrin rẹ̀
àti Jeaterai ọmọkùnrin rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.