1 Kronika 6:16
1 Chronicles 6:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.
1 Chronicles 6:16 in English
1 Chronicles 6:16 · Berean Standard Bible
The sons of Levi: Gershom,* Kohath, and Merari.
Context
14Asariah baba Seraiah,
pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki. 15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari. 16Àwọn ọmọ Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari. 17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.