Native Bible

1 Chronicles 6:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki.

1 Chronicles 6:14 in English

1 Chronicles 6:14 · Berean Standard Bible

Azariah was the father of Seraiah, and Seraiah was the father of Jehozadak.*

Context

12Ahitubu baba Sadoku. Sadoku baba Ṣallumu, 13Ṣallumu baba Hilkiah, Hilkiah baba Asariah, 14Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki. 15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari. 16Àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.