Native Bible

1 Chronicles 6:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari.

1 Chronicles 6:15 in English

1 Chronicles 6:15 · Berean Standard Bible

Jehozadak went into captivity when the LORD sent Judah and Jerusalem into exile by the hand of Nebuchadnezzar.

Context

13Ṣallumu baba Hilkiah, Hilkiah baba Asariah, 14Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki. 15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari. 16Àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari. 17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.