Native Bible

1 Chronicles 24:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ.

1 Chronicles 24:28 in English

1 Chronicles 24:28 · Berean Standard Bible

From Mahli: Eleazar, who had no sons.

Context

26Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno. 27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri. 28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. 29Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli. 30Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti Jerimoti. Èyí ni àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.