Native Bible

1 Chronicles 24:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli.

1 Chronicles 24:29 in English

1 Chronicles 24:29 · Berean Standard Bible

From Kish: Jerahmeel the son of Kish.

Context

27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri. 28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. 29Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli. 30Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti Jerimoti. Èyí ni àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. 31Wọ́n sì ṣé kèké gẹ́gẹ́ bí àwọn arákùnrin wọn àwọn ọmọ Aaroni ṣe ṣẹ́, níwájú ọba Dafidi àti Sadoku, Ahimeleki, àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Lefi. Àwọn ìdílé àgbàgbà arákùnrin wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀ lórí àwọn arákùnrin wọn kéékèèké.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.