Native Bible

1 Chronicles 24:30 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti Jerimoti. Èyí ni àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.

1 Chronicles 24:30 in English

1 Chronicles 24:30 · Berean Standard Bible

And the sons of Mushi: Mahli, Eder, and Jerimoth.* These were the sons of the Levites, according to their families.

Context

28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. 29Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli. 30Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti Jerimoti. Èyí ni àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. 31Wọ́n sì ṣé kèké gẹ́gẹ́ bí àwọn arákùnrin wọn àwọn ọmọ Aaroni ṣe ṣẹ́, níwájú ọba Dafidi àti Sadoku, Ahimeleki, àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Lefi. Àwọn ìdílé àgbàgbà arákùnrin wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀ lórí àwọn arákùnrin wọn kéékèèké.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.