Native Bible

1 Chronicles 24:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri.

1 Chronicles 24:27 in English

1 Chronicles 24:27 · Berean Standard Bible

The descendants of Merari from Jaaziah: Beno, Shoham, Zaccur, and Ibri.

Context

25Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah. 26Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno. 27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri. 28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. 29Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.