Native Bible

1 Chronicles 24:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah.

1 Chronicles 24:25 in English

1 Chronicles 24:25 · Berean Standard Bible

The brother of Micah: Isshiah; from the sons of Isshiah: Zechariah.

Context

23Àwọn ọmọ Hebroni: Jeriah alákọ́kọ́, Amariah ẹlẹ́ẹ̀kejì, Jahasieli ẹlẹ́ẹ̀kẹta àti Jekameamu ẹlẹ́ẹ̀kẹrin. 24Àwọn ọmọ Usieli: Mika; nínú àwọn ọmọ Mika: Ṣamiri. 25Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah. 26Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno. 27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.