Native Bible

1 Chronicles 24:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno.

1 Chronicles 24:26 in English

1 Chronicles 24:26 · Berean Standard Bible

The sons of Merari: Mahli and Mushi. The son of Jaaziah: Beno.

Context

24Àwọn ọmọ Usieli: Mika; nínú àwọn ọmọ Mika: Ṣamiri. 25Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah. 26Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno. 27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri. 28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.