Native Bible

1 Chronicles 1:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki.

1 Chronicles 1:36 in English

1 Chronicles 1:36 · Berean Standard Bible

The sons of Eliphaz: Teman, Omar, Zepho,* Gatam, and Kenaz; and by Timna, Amalek.

Context

34Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki. Àwọn ọmọ Isaaki: Esau àti Israẹli. 35Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora. 36Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki. 37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa. 38Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.