Native Bible

1 Chronicles 1:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora.

1 Chronicles 1:35 in English

1 Chronicles 1:35 · Berean Standard Bible

The sons of Esau: Eliphaz, Reuel, Jeush, Jalam, and Korah.

Context

33Àwọn ọmọ Midiani: Efani, Eferi, Hanoku, Abida àti Eldaa. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Ketura. 34Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki. Àwọn ọmọ Isaaki: Esau àti Israẹli. 35Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora. 36Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki. 37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.