1 Kronika 1:34
1 Chronicles 1:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki. Àwọn ọmọ Isaaki: Esau àti Israẹli.
1 Chronicles 1:34 in English
1 Chronicles 1:34 · Berean Standard Bible
Abraham was the father of Isaac. The sons of Isaac: Esau and Israel.
Context
32Àwọn ọmọ Ketura, obìnrin Abrahamu:
Simrani, Jokṣani Medani, Midiani Iṣbaki àti Ṣua.
Àwọn ọmọ Jokṣani:
Ṣeba àti Dedani. 33Àwọn ọmọ Midiani:
Efani, Eferi, Hanoku, Abida àti Eldaa.
Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Ketura. 34Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki.
Àwọn ọmọ Isaaki:
Esau àti Israẹli. 35Àwọn ọmọ Esau:
Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora. 36Àwọn ọmọ Elifasi:
Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi;
láti Timna: Amaleki.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.