Native Bible

1 Chronicles 1:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

1 Chronicles 1:37 in English

1 Chronicles 1:37 · Berean Standard Bible

The sons of Reuel: Nahath, Zerah, Shammah, and Mizzah.

Context

35Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora. 36Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki. 37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa. 38Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani. 39Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.