Native Bible

1 Chronicles 1:38 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.

1 Chronicles 1:38 in English

1 Chronicles 1:38 · Berean Standard Bible

The sons of Seir: Lotan, Shobal, Zibeon, Anah, Dishon, Ezer, and Dishan.

Context

36Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki. 37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa. 38Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani. 39Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani. 40Àwọn ọmọ Ṣobali: Afiani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti Onamu. Àwọn ọmọ Sibeoni: Aiah àti Ana.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.