Native Bible

Psalms 78:46 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fi ọkà wọn fún láńtata, àwọn ìre oko wọn fún eṣú.

Psalms 78:46 in English

Psalms 78:46 · Berean Standard Bible

He gave their crops to the grasshopper, the fruit of their labor to the locust.

Context

44Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀; wọn kò lè mu láti odò wọn. 45Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run, àti ọ̀pọ̀lọ́ tí ó bá wọn jẹun. 46Ó fi ọkà wọn fún láńtata, àwọn ìre oko wọn fún eṣú. 47Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́ ó bá èso sikamore wọn jẹ́. 48Ó fi ohun ọ̀sìn wọn fún yìnyín, agbo ẹran wọn fún mọ̀nàmọ́ná.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.