Saamu 78:47
Psalms 78:47 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́ ó bá èso sikamore wọn jẹ́.
Psalms 78:47 in English
Psalms 78:47 · Berean Standard Bible
He killed their vines with hailstones and their sycamore-figs with sleet.*
Context
45Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run,
àti ọ̀pọ̀lọ́ tí ó bá wọn jẹun. 46Ó fi ọkà wọn fún láńtata,
àwọn ìre oko wọn fún eṣú. 47Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́
ó bá èso sikamore wọn jẹ́. 48Ó fi ohun ọ̀sìn wọn fún yìnyín,
agbo ẹran wọn fún mọ̀nàmọ́ná. 49Ó mú kíkorò ìbínú rẹ̀ wá sí wọn lára,
ìrunú àti ìkáàánú, àti ìpọ́njú,
nípa rírán angẹli apanirun sí wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.