Saamu 78:45
Psalms 78:45 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run, àti ọ̀pọ̀lọ́ tí ó bá wọn jẹun.
Psalms 78:45 in English
Psalms 78:45 · Berean Standard Bible
He sent swarms of flies that devoured them, and frogs that devastated them.
Context
43ní ọjọ́ tí ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ hàn ní Ejibiti,
àti iṣẹ́ àmì rẹ̀ ni ẹkùn Ṣoani 44Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀;
wọn kò lè mu láti odò wọn. 45Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run,
àti ọ̀pọ̀lọ́ tí ó bá wọn jẹun. 46Ó fi ọkà wọn fún láńtata,
àwọn ìre oko wọn fún eṣú. 47Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́
ó bá èso sikamore wọn jẹ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.