Saamu 78:44
Psalms 78:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀; wọn kò lè mu láti odò wọn.
Psalms 78:44 in English
Psalms 78:44 · Berean Standard Bible
He turned their rivers to blood, and from their streams they could not drink.
Context
42Wọ́n kò rántí agbára rẹ̀:
ní ọjọ́ tí ó rà wọ́n padà lọ́wọ́ àwọn aninilára, 43ní ọjọ́ tí ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ hàn ní Ejibiti,
àti iṣẹ́ àmì rẹ̀ ni ẹkùn Ṣoani 44Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀;
wọn kò lè mu láti odò wọn. 45Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run,
àti ọ̀pọ̀lọ́ tí ó bá wọn jẹun. 46Ó fi ọkà wọn fún láńtata,
àwọn ìre oko wọn fún eṣú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.