Saamu 78:42
Psalms 78:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n kò rántí agbára rẹ̀: ní ọjọ́ tí ó rà wọ́n padà lọ́wọ́ àwọn aninilára,
Psalms 78:42 in English
Psalms 78:42 · Berean Standard Bible
They did not remember His power *— the day He redeemed them from the adversary,
Context
40Nígbà gbogbo ní wọn ń ṣọ̀tẹ̀ sí i ní aginjù
wọn mú un bínú nínú ilẹ̀ tí ó di ahoro! 41Síwájú àti síwájú wọ́n dán Ọlọ́run wò;
wọ́n mú ẹni mímọ́ Israẹli bínú. 42Wọ́n kò rántí agbára rẹ̀:
ní ọjọ́ tí ó rà wọ́n padà lọ́wọ́ àwọn aninilára, 43ní ọjọ́ tí ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ hàn ní Ejibiti,
àti iṣẹ́ àmì rẹ̀ ni ẹkùn Ṣoani 44Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀;
wọn kò lè mu láti odò wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.