Saamu 71:8
Psalms 71:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi, ó ń sọ ti ọlá rẹ ní ọjọ́ gbogbo.
Psalms 71:8 in English
Psalms 71:8 · Berean Standard Bible
My mouth is filled with Your praise and with Your splendor all day long.
Context
6Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi;
Ìwọ mú mi jáde láti inú ìyá mi wá
èmi ó máa yìn ọ́ títí láé. 7Mo di àmì fún ọ̀pọ̀ ènìyàn,
ṣùgbọ́n ìwọ ni ààbò mi tí ó lágbára. 8Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi,
ó ń sọ ti ọlá rẹ ní ọjọ́ gbogbo. 9Má ṣe ta mí nù ní ọjọ́ ogbó mi,
má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ nígbà tí kò sí okun mọ́. 10Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀-òdì sí mi,
àwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.