Saamu 71:10
Psalms 71:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀-òdì sí mi, àwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀.
Psalms 71:10 in English
Psalms 71:10 · Berean Standard Bible
For my enemies speak against me, and those who lie in wait for my life conspire,
Context
8Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi,
ó ń sọ ti ọlá rẹ ní ọjọ́ gbogbo. 9Má ṣe ta mí nù ní ọjọ́ ogbó mi,
má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ nígbà tí kò sí okun mọ́. 10Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀-òdì sí mi,
àwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀. 11Wọ́n wí pé, “Ọlọ́run ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀;
lépa rẹ̀ kí ẹ sì mu,
nítorí kò sí ẹni tí yóò gbà á.” 12Má ṣe jìnnà sí mi, Ọlọ́run;
wa kánkán, Ọlọ́run mi, láti ràn mí lọ́wọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.