Native Bible

Psalms 116:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa.

Psalms 116:13 in English

Psalms 116:13 · Berean Standard Bible

I will lift the cup of salvation and call on the name of the LORD.

Context

11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”. 12Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi? 13Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa. 14Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa ní ojú àwọn ènìyàn rẹ̀. 15Iyebíye ní ojú Olúwa àti ikú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.