Saamu 116:15
Psalms 116:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Iyebíye ní ojú Olúwa àti ikú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.
Psalms 116:15 in English
Psalms 116:15 · Berean Standard Bible
Precious in the sight of the LORD is the death of His saints.
Context
13Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè
èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa. 14Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa
ní ojú àwọn ènìyàn rẹ̀. 15Iyebíye ní ojú Olúwa
àti ikú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀. 16Olúwa, nítòótọ́ ìránṣẹ́ rẹ ni mo jẹ́;
èmi ni ìránṣẹ́ rẹ, ọmọ ìránṣẹ́bìnrin rẹ;
ó ti tú mi sílẹ̀ nínú ìdè mi. 17Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ
èmi yóò sì ké pe orúkọ Olúwa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.