Native Bible

Psalms 116:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi?

Psalms 116:12 in English

Psalms 116:12 · Berean Standard Bible

How can I repay the LORD for all His goodness to me?

Context

10Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”. 11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”. 12Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi? 13Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa. 14Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa ní ojú àwọn ènìyàn rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.