Native Bible

Psalms 116:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”.

Psalms 116:10 in English

Psalms 116:10 · Berean Standard Bible

I believed, therefore I said,* “I am greatly afflicted.”

Context

8Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi kúrò lọ́wọ́ ikú, ojú mi kúrò lọ́wọ́ omijé, àti ẹsẹ̀ mi kúrò lọ́wọ́ ìṣubú, 9nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa ní ilẹ̀ alààyè. 10Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”. 11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”. 12Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.