Native Bible

Psalms 116:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa ní ilẹ̀ alààyè.

Psalms 116:9 in English

Psalms 116:9 · Berean Standard Bible

I will walk before the LORD in the land of the living.

Context

7Padà, ìwọ ọkàn mi, sí ibi ìsinmi rẹ, nítorí Olúwa ṣe dáradára sí ọ. 8Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi kúrò lọ́wọ́ ikú, ojú mi kúrò lọ́wọ́ omijé, àti ẹsẹ̀ mi kúrò lọ́wọ́ ìṣubú, 9nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa ní ilẹ̀ alààyè. 10Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”. 11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.