Native Bible

Psalms 116:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”.

Psalms 116:11 in English

Psalms 116:11 · Berean Standard Bible

In my alarm I said, “All men are liars!”

Context

9nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa ní ilẹ̀ alààyè. 10Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”. 11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, “Èké ni gbogbo ènìyàn”. 12Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi? 13Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.