Saamu 115:15
Psalms 115:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé.
Psalms 115:15 in English
Psalms 115:15 · Berean Standard Bible
May you be blessed by the LORD, the Maker of heaven and earth.
Context
13Ìbùkún ni fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa,
àti kékeré àti ńlá. 14Olúwa yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú,
ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ̀. 15Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa
ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé. 16Ọ̀run àní ọ̀run ni ti Olúwa:
ṣùgbọ́n ayé ló fi fún ọmọ ènìyàn. 17Òkú kò lè yìn Olúwa,
tàbí ẹni tí ó ti lọ sí ìsàlẹ̀ ìdákẹ́ jẹ́ẹ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.