Saamu 115:14
Psalms 115:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú, ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ̀.
Psalms 115:14 in English
Psalms 115:14 · Berean Standard Bible
May the LORD give you increase, both you and your children.
Context
12Olúwa tí ń ṣe ìrántí wa; yóò bùkún ilé Israẹli;
yóò bùkún ilé Aaroni. 13Ìbùkún ni fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa,
àti kékeré àti ńlá. 14Olúwa yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú,
ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ̀. 15Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa
ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé. 16Ọ̀run àní ọ̀run ni ti Olúwa:
ṣùgbọ́n ayé ló fi fún ọmọ ènìyàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.