Native Bible

Psalms 115:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìbùkún ni fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa, àti kékeré àti ńlá.

Psalms 115:13 in English

Psalms 115:13 · Berean Standard Bible

He will bless those who fear the LORD— small and great alike.

Context

11Ẹ̀ yin tí ó bẹ̀rù Olúwa, gbẹ́kẹ̀lé Olúwa: òun ní ìrànwọ́ àti ààbò wọn. 12Olúwa tí ń ṣe ìrántí wa; yóò bùkún ilé Israẹli; yóò bùkún ilé Aaroni. 13Ìbùkún ni fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa, àti kékeré àti ńlá. 14Olúwa yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú, ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ̀. 15Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.