Native Bible

Psalms 115:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Òkú kò lè yìn Olúwa, tàbí ẹni tí ó ti lọ sí ìsàlẹ̀ ìdákẹ́ jẹ́ẹ́.

Psalms 115:17 in English

Psalms 115:17 · Berean Standard Bible

It is not the dead who praise the LORD, nor any who descend into silence.

Context

15Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé. 16Ọ̀run àní ọ̀run ni ti Olúwa: ṣùgbọ́n ayé ló fi fún ọmọ ènìyàn. 17Òkú kò lè yìn Olúwa, tàbí ẹni tí ó ti lọ sí ìsàlẹ̀ ìdákẹ́ jẹ́ẹ́. 18Ṣùgbọ́n àwa ó fi ìbùkún fún Olúwa láti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé. Ẹ yin Olúwa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.