Saamu 108:4
Psalms 108:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí tí o tóbi ní àánú rẹ ju àwọn ọ̀run lọ àti òdodo rẹ dé àwọsánmọ̀.
Psalms 108:4 in English
Psalms 108:4 · Berean Standard Bible
For Your loving devotion extends beyond the heavens, and Your faithfulness reaches to the clouds.
Context
2Jí ohun èlò orin àti haapu!
Èmi ó jí ní kùtùkùtù, 3èmi ó yìn ọ́, Olúwa, nínú àwọn orílẹ̀-èdè,
èmi ó kọrin rẹ nínú àwọn ènìyàn. 4Nítorí tí o tóbi ní àánú rẹ
ju àwọn ọ̀run lọ
àti òdodo rẹ dé àwọsánmọ̀. 5Gbé ara rẹ ga, Ọlọ́run, lórí àwọn ọ̀run,
àti ògo rẹ lórí gbogbo ayé. 6Kí a sì lè gba àwọn olùfẹ́ rẹ là;
fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ ṣe ìgbàlà,
kí o sì dá mi lóhùn
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.