Native Bible

Psalms 108:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jí ohun èlò orin àti haapu! Èmi ó jí ní kùtùkùtù,

Psalms 108:2 in English

Psalms 108:2 · Berean Standard Bible

Awake, O harp and lyre! I will awaken the dawn.

Context

1Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣin èmi ó máa kọrin, èmi ó máa fi ọkàn mi kọrin. 2Jí ohun èlò orin àti haapu! Èmi ó jí ní kùtùkùtù, 3èmi ó yìn ọ́, Olúwa, nínú àwọn orílẹ̀-èdè, èmi ó kọrin rẹ nínú àwọn ènìyàn. 4Nítorí tí o tóbi ní àánú rẹ ju àwọn ọ̀run lọ àti òdodo rẹ dé àwọsánmọ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.