Native Bible

Psalms 108:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣin èmi ó máa kọrin, èmi ó máa fi ọkàn mi kọrin.

Psalms 108:1 in English

Psalms 108:1 · Berean Standard Bible

My heart is steadfast, O God; I will sing and make music with all my being.*

Context

1Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣin èmi ó máa kọrin, èmi ó máa fi ọkàn mi kọrin. 2Jí ohun èlò orin àti haapu! Èmi ó jí ní kùtùkùtù, 3èmi ó yìn ọ́, Olúwa, nínú àwọn orílẹ̀-èdè, èmi ó kọrin rẹ nínú àwọn ènìyàn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.